Aye Ole-Infinity

歌手 : Infinity
专辑 : Olori Oko
语种 : 英语
时长 : 04:01

DOLBY 杜比全景声 下载

臻品母带 下载

臻品全景声 下载

臻品音质

HIRES Hi-Res 下载

FLAC 无损flac 百度云网盘下载

APE 无损ape 格式下载

320MP3 极高mp3 歌曲下载

128MP3 标准mp3 百度网盘下载

192OGG 较高ogg 下载

192AAC 较高aac 下载

96AAC 标准aac 百度云下载

Loading...

TXT Aye Ole-Infinity 文本歌词

Hmmmm
Omo eniyan
F'eti si
Oro agba bi o she l'owuro
A she lowo ale
1
Bowun ko pe titi iya aye wa o n bo wa d'opin
Aimola eda lo mu eda saniyan ra
Olorun ti seleri oro baba ko ni ye
Aini gbaggbao lo mu eda raropin
Bi okun n fo
Ti osa n sa
Otito wa laaye
Igbabo ni orisun ohun gbogbo
Oh Hu hu hu
Aye yi ko male
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
Oh Hu hu hu
Aye yi ko male o
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
Hu hu hu
Aye yi ko male
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
Oh Hu hu hu
Aye yi ko male o
Aye ole fun eni to ni gbagbo pe aye ole
2
Oni suuru ape koto je koni jebaje
Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi
F'oju re womi ore k'Oluwa le foju re wo e
Abiku ti d'abiye ninu aye mi
Oni suuru ape koto je koni jebaje
Ai mani suuru lo n mu are eni bo wa debi
F'oju re womi ore k'Oluwa le foju re wo e
Abiku ti d'abiye ninu aye mi
Repeat 35x
Ha ha ha
Aye re ko ma ni le
To ba ba Olorun rin o sho ri re
Bowun ko pe titi iya aye wa o n bo wa d'opin